Irinṣẹ́ òǹkà ọdún ti wà láti ka iye ọdún tó leè lò láyé

Published

Njẹ́ o mọ̀ pé, iye ọdún tó ṣeé ṣe kí gbogbo ènìyàn lò láyé, ti fi ọdún méje pọ̀ si láti ọdún 1990?

Irinṣẹ́ òǹkà ọdún yìí, yóò ràn ọ́ lọ́wọ́ láti ṣe ìṣìrò tìrẹ̀, ní ìbámu pẹ̀lú orílẹ̀èdè to ti wá.

Ọdun mejilelaadọrin nireti wa pe o jẹ ọdun to kere ju ti ẹda yoo lo laye - aadọrin ọdun fun ọkunrin, marundinlọgọrin fun obinrin. Ṣugbọn, eyi n yipada pẹlu ọjọ ori. Fun apẹẹrẹ,ireti wa pe ẹni ti o ti pe ọdun mọkandinlaadọrin yoo lo ọdun mẹtadinlogun si.

Fo Móríwú kọjá kí o tẹ̀síwájú

Móríwú

  • Awọn afurasi ajọmọgbe kọ ẹyin si ẹrọ ayaworan
  • Imaamu agba fun ilu Ilaro, Alhaji Tajudeen Adewumi
  • Opeyemi Sanyaolu wọ kaba ankara alawọ omi ọsan, o we gele ankara naa, o fi iborun kọrun, o gbe oju soke, o si n lọ ika rẹ
  • Charles Okocha wo aso pupa, o gbe bẹliiti ija to ja dani
  • Awọn ọmọde meji gbe ejo sọrun
  • Oreoluwa Osoba jokoo, o wọ asọ tshirt funfun, o kọ oju fila oloyinbo to de si ẹyin, o gbe aja kekere kan lọwọ
  • Aworan Ọgbẹni Adeloye
  • Aworan arabinrin kan to wọ aṣọ jẹsi ẹgbẹ agbabọlu Arsenal n sọrọ
  • Balogun Odeyimika Oderinlo to ja ogun marundinlaadoje fun ilẹ Ibadan
  • Ẹyẹ igun duro sori orule
  • Ademola Adeleke, tii se gomina ipinlẹ Osun, ati egbọn re Dupẹ Adeleke Sanni di mọra wọn
  • Aworan Tope Osoba lasiko to ṣabẹwo si BBC Yoruba
  • Aworan akọrin Ẹmi, Bisi Manuel
  • Aworan Kọla Oyewọ
  • Aworan osere sinima, Bọlaji Ogunmọla bi o se n ba BBC sọrọ

Ìròyìn tí àwọn ènìyàn fẹ́ràn jùlọ