Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́

Àkọlé fọ́nrán ohùn, Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́
Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́
Published

Baalu ti Seyi Makinde fowo ilu ra ko le nipa kankan lori eto aabo l'Oyo

Gbaga lẹnu rẹ?

Emi kọ o, onimọ nipa eto aabo kan lo sọ bẹẹ

Ki lo ri to fi sọ bẹẹ gan an

O ni kii ṣe iru awọn baalu naa lawọn eleto aabo maa n lo

ẹnh ẹnh

wo o ọrọ pọ ninu iwe kọbọ, lọ ka yooku loju opo wa

'''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''

Mo wa ninu ile lọjọ nigba tawọn DSS n yinbọn lakọ lakọ lati pa mi sile n'Ibadan, amọ, wọn o ri mi

Oloye Sunday Igboho lo sọ pe gbogbo nnkan tawọn ẹṣọ DSS ṣe nile oun loun ri

Ati bi wọn ṣe pa ologbo ti wọn ro pe oun ni

Kini Igboho wa sọ pe oun lo to fi moribọ

Alaye wa lori ikanni BBC Yoruba

''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''

Atoto arere!

Ki lo n ṣẹlẹ ẹ?

Ẹ ma gbagbe pe laago mẹfa irọlẹ ọtunla ọjọ Ẹti ni itakurọsọ

Laarin awọn oludije sipo gomina Osun yoo waye lori ikanni BBC Yoruba

Nibẹ lawọn oludije yoo ti sọ ohun ti wọn fẹ ṣe ti wọn wọle

Fun ẹkunrẹrẹ